
在手机上保存,获得更好体验
OP DOT gbewalo ooo
2t upon the beats
Omomomoriamo ooo
(DJ OP DOT I love you)
Ungba Ungba Ungba Alagbe Ungba Ungba Ungba
Qdot loruko mi timba ni gbetiti gbegbe ungbe ungbe GBEMIDEBE
Ki l'onje ta jeri
Gbemidebe!
Packaging lo pa Lekki
Gbemidebe!
Won ni o se kan to seri
Gbemidebe!
Kosi barber ti o le geri
Gbemidebe!
Haircut lo ma yato
Gbemidebe!
Happy hour lori molly
Gbemidebe!
Idunnu lo subu layo
Gbemidebe!
Alagbe le salaye
Gbemidebe!
O ngbe mi trabaye
Gbemidebe!
Irole lo ma nwe
Gbemidebe!
Awon omo mi loruloru
Gbemidebe!
Kafaya (Gbemidebe!)
Karimo (Gbemidebe!)
Jenifer (Gbemidebe!)
Ori mi lo fe fa
Gbemidebe!
Alhaja Memuna
Gbemidebe!
Eleha to nse stripper
Gbemidebe!
Awa o ki nawo fun egun
Gbemidebe!
Be se ndaso boju
Gbemidebe!
Akori koda
Gbemidebe!
Buju ti p'oruko da
Gbemidebe!
Odori odori (Gbemidebe!)
Alhaja lohun o bori
Gbemidebe!
Ogbowo ko fe sori
Gbemidebe!
Mo mo po momi
Gbemidebe!
Lo se nfobo lo mi
Gbemidebe!
Lo bere mi n'ilu Ibadan
Gbemidebe!
Won ma je ko m'otan
Gbemidebe!
Igboro mo mi
Gbemidebe!
Igboho oosa gan mo mi
Gbemidebe!
Omo anibon majale
Gbemidebe!
Omo ajale ma gbowo
Gbemidebe!
Ororun mi ni
Gbemidebe!
O ri pampa
Gbemidebe!
Idi nla gbamgba
Gbemidebe!
Ko n'ise lapa
Gbemidebe!
Eni tan bo to nbo aja
Gbemidebe!
Ti picker ba gbowo lo
Gbemidebe!
Middle man lo je gbese
Gbemidebe!
B'ebi ba pa were
Gbemidebe!
Were ma ja w'oja
Gbemidebe!
Egun ara orun
Gbemidebe!
Ohun gan hustle laye
Gbemidebe!
Trust nobody
Gbemidebe!
Olamide (Gbemidebe!)
Ko m'onu Enimony
Gbemidebe!
Ninu aye (Gbemidebe!)
Won njoju anybody
Gbemidebe!
IBD Dende (Gbemidebe!)
Alaye ma ngbemidebe
Gbemidebe!
MC Oluomo (Gbemidebe!)
L'ekole omojuomo
Gbemidebe!
Arowolo lo nta motor
Gbemidebe!
N'ilu Atlanta
Gbemidebe!
Eba nki Mama Kay o
Gbemidebe!
Mummy OP DOT
Gbemidebe!
Eyan Qdot
Gbemidebe!
Mayegun gbogbo Dubai
Gbemidebe!
Ijebu o fowo sere
Gbemidebe!
Won f'ise sere
Gbemidebe!
Mo mo Tunde Adigun
Gbemidebe!
Adigun abule sowo
Gbemidebe!
Kogbagiidi (Gbemidebe!)
Billique 60 - 40
Gbemidebe!
Bukunmi Mama Meto
Gbemidebe!
Climax lo nse visa
Gbemidebe!
Dakun ma se transfer
Gbemidebe!
Kaala (Gbemidebe!)
Ranju (Gbemidebe!)
Akala gbogbo Golo
Gbemidebe!
Momo alase gbogbo Turkey
Gbemidebe!
Otunba cash
Gbemidebe!
Mo mo Sanwo Ayanlu
Gbemidebe!
Akinrogun owo mi da
Gbemidebe!
Mo ni mo moja omode
Gbemidebe!
Eyan Okoko
Gbemidebe!
Okoko dakun ma yinbon
Gbemidebe!
Kunle poly (Gbemidebe!)
Eyan Barryshine
Gbemidebe!
Gbemidebe
Gbemidebe!
Oni motor gb'emi sare (Gbemidebe!)
OP DOT Gbemidebe
2t Gbemidebe
(2t on the mix)