
时间:2025-02-08
在手机上保存,获得更好体验
Mò ń bọ̀
Alhaji mò ń bọ̀
Musiliu mi (Musiliu mi)
Ayédádé ó wu Ọlọ́hun ló dá Àyìndé mi lọ́lá
Ó wu Ọlọ́hun ló dá Àyìndé mi lọ́lá
Ganiyu dà? Ó wu Ọlọ́hun ló dá Àyìndé mi lọ́lá
Ó wu Ọlọ́hun ló dá Àyìndé mi lọ́lá
Ọ̀tá ẹ yé ṣe làlé òfo o
Ó wu Ọlọ́hun ló dá Àyìndé mi lọ́lá
Àyìndé adé o ò ní m’òṣì
Igbó kan ò ta kókó rí pé kí kán má jẹ’lé
Wàá máa rí’lé bọ́sí
Wàá máa r’óde já Àyìndé Musiliu Ayédáadé
Òṣì ò ní ṣọ̀rẹ́ ẹ Àyìndé àdúà ẹ ti gbà MC
Musiliu mi (Musiliu mi)
Àdùẹ́ f’Ọ́lọ́hun Àyìndé gbogbo oyè tí èèyàn bá ń joyè
Tó bá ń joyè, tó bá ń dupò
Ìbáà jẹ́ olórí ẹgbẹ́ Ìbáà jẹ́ olórí ìlú
Tó bá fi ba d’órí President number 1
Ọpẹ́ ni kó máa ṣe kó dúpẹ́ f’Ọ́lọ́hun (Adé orí ọ̀kín)
Àyìndé Ọlọ́hun ló ní ó rí bẹ́ẹ̀ láti kékeré ẹ Àyìndé Musiliu mi
Kó o tó di President ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn lati ń gbà á lérò
Lati ń gbà á ní àdúrà
Wí pé o máa di President Àyìndé Musiliu o
Adúpẹ́ fọlọhun ọba àwa ń gbà á ní àdúrà ni
Ọlọ́hun Ọba lọba tó láṣẹ Wasiu Àyìndé
Àṣẹ lọ́wọ́ ẹ̀ ló wà arábámbí mo dúpẹ́ Ọlọ́hun Àyìndé
Níṣojú ẹ̀mí mi (Musiliu mi)
O fi President o fi kún òye ẹ
O jẹ treasurer, o jẹ state, o jẹ branch
Láti branch láti branch Àyìndé ò ń túmọ̀ náà bọ̀
Treasurer, chairman, o bọ́ sórí state ó jẹ treasurer
Ó jẹ chairman, o tún wá bọ́ s9kè pátápátá lọ́hùn-ún
Olórí là ń f’orí fún ọ (olórí là ń f’orí fún)
Àyìndé Olórí là ń f’orí fún ọ (olórí là ń f’orí fún)
Ayédáadé Àyìndé Musiliu olórí là ń f’orí fún)
Àyìndé ọ̀rọ̀ bí ẹkún (kò ń b’olúwa)
Ọ̀rọ̀ bí òṣé p(kò ń b’ólúwa)
(Èdùmàrè kò má fi sọ́rọ̀ ẹ Àyìndé Musiliu ọmọ Akínsànyà o)
Ebi ni wọ́n ń dá pa’ra wọn (ìyà ni wọ́n ń dá jẹ’ra wọn)
B’ẹ́gbẹ̀rún òtòṣì bá yan ọlọ́rọ̀ lódì (ebi ni wọ́n ń dá pa’ra wọn)
Mò ń tẹnu mọ lójoojúmọ́ ayé mi Wasiu Àyìndé
Èèyàn tó bá ti d’olórí ìwọ ni bàbá everybody Ayédáadé mi Àyìndé o
Ah! Ilé lọ́wọ́ ẹ ló wà MC Musiliu mi (MC Musiliu mi o)
Èyí ni’hun tá a fẹ́ t’Ọ́lọ́hun Ọba ti ṣé
Ihun tá a fẹ́ t’Ọ́lọ́hun Ọba ti ṣé
Ìbá ẹ tó ń jó o ti fi jó nǹkan
Kò dẹ̀ ní bàjẹ́ bó w’ọlá Ọlọ́hun
Àyìndé wọ́n ma tò lẹ́yìn ẹ
(Wọ́n ó máa tò lẹ́yìn ẹ o)
Alága Èkìtì ní n kí ẹ Musiliu
Ọlọ́pàá ẹ̀rọ̀ ó ní n bá’un kí ẹ Àyìndé
Ẹ jọ̀ọ́ èmi fẹ́ ṣe fàájì ní tèmi o
Egúngún Ayéda (Egúngún Ayédáadé)
Oore ni oore ni
Oore ni Àyìndé oore ni
Musiliu Àyìndé Akínsànyà oore ni oore ni
Ibi ẹ lé wa dé yìí náà o oore ni
Àwa ò mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ká tó sáré
B’ẹ́yin gan mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ni ẹ ò ní lé wa
(Oore ni oore ni)
(Oore ni oore ni)
(Ibi ẹ lé wa dé yìí náà o oore ni)
(Àwa ò mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ká tó sáré)
(B’ẹ́yin gan mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ni ẹ ò ní lé wa)
Ọmọ ayé alénibọ́rọ̀ Àyìndé mi Wasiu arábámbí
Ìgbà tó wá rí bẹ́ẹ̀ ìwọ l’olórí ilé ìwọ l’olórí ẹbí
Ọ̀rọ̀ tí ìwọ bá sọ àṣẹ ni
Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh
Musiliu ọmọ Akínsànyà ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh
Ọmọ Àbẹ̀ní ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh
Àyìndé ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o ah
Èyí tí o wí yẹn arọ̀ ti rọ̀ mọ
Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ Ayédáadé
(Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh)
Ọmọ mi ni ọmọ’re ni
(Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh)
(Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh)
(Èyí tí o wí yẹn arọ̀ ti rọ̀ mọ)
(Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ Ayédáadé)
Ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh
Musiliu ọ̀rọ̀ ẹ dàṣẹ o eh
KC Oore ni oore ni
Oore ni oore ni
Ibi ẹ lé wa dé yìí náà o oore ni
Àwa ò mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ká tó sáré
B’ẹ́yin gan mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ni ẹ ò ní lé wa
(Oore ni oore ni)
(Oore ni oore ni)
(Ibi ẹ lé wa dé yìí náà o oore ni)
(Àwa ò mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ ni ká tó sáré)
(B’ẹ́yin gan mọ̀ pé bẹ́ẹ̀ni ẹ ò ní lé wa)
Àyìndé mi Musiliu (egúngún Ayédáadé)
Ọlọ́hun Ọba ti (Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Ìlẹ̀kùn ti ṣí ará mi (Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Gbogbo 36 States ilẹ̀kùn tí ṣí ará mi o
(Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Àsìkò tì ẹ ewé làwa ní wẹ́wẹ́ fún gbogbo National Union
(Ọlọ́hun Ọba ti ṣe)
Èyí tí àwa bá fẹ́ òun ni ìjọba máa mú lò (Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Àyìndé ọwọ́ ẹ ló wà (Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Ìwọ ni President gbogbo National Union (Ọlọ́hun Ọba ti ṣé)
Kò s’ẹ́ni tí ó yọ’hùn ẹ bó wọlá Ọlọ́hun
(Ọlọ́hun Ọbá ti ṣé)
Okay, mo ti pàṣẹ ìyẹn dání
Ọmọ bàbá ẹ
(Arábámbí olúọmọ of Lagos Máyégún General)
(Gbogbo ilé ń kí ẹ)
Ọmọ ti bàbá ẹ o
(Arábámbí olúọmọ of Lagos Máyégún General)
(Gbogbo ilé ń kí ẹ)
Ọmọ bàbá ẹ
(Arábámbí olúọmọ of Lagos Máyégún General)
(Gbogbo ilé ń kí ẹ)
Ọmọ mi Ọlọ́fọ̀ọ́ọ̀rọ̀, ọmọ bàbá o
(Arábámbí olúọmọ of Lagos Máyégún General)
(Gbogbo ilé ń kí ẹ)
Abímbọ́lá Thomas Scoda Tìẹ́pọ̀
Ọmọ Bàbá ẹ (Arábámbí olúọmọ of Lagos)
(Máyégún General gbogbo ilé ń kí ẹ)
Ọlọ́fọ̀ọ́ọ̀rọ̀ àgbàlagbà ni ẹ́
Àgbà lẹtù ọmọdé lawó o kú àdúrótì
Àdúà ẹ ti gbà Àyìndé
Awo presi o (awo presi o)
Ọlọ́fọ̀ọ́ọ̀rọ̀ awo presi o (awo presi o)
Awo Àyìndé Musiliu (awo presi o)
Ọlọ́fọ̀ọ́ọ̀rọ̀ l’Ékìtì awo t’Àyìndé Musiliu (awo presi o)
Àyìndé wọn ò pọ̀ o (àtúnniṣe ò pọ̀ ó)
Wọn ò pọ̀ o (atúnniṣe ò pọ̀ o)
(Atúnniṣe ò pọ̀ o bí ẹní bàjẹ́ o àdúà lẹbọ)
Musiliu Ọlọ́fọ̀ọ́ọ̀rọ̀ àwọn atúnniṣe ò pọ̀ o
(Bí oníbàjẹ́ àdúà lẹbọ)
Bo gúnyán lẹlẹ dè wọ́n o
(Bó bá dálẹ́ wàá jẹ)
Bo wẹ’kà lẹlẹ dè wọ́n o Àyìndé
(Bó bá dálẹ́ wàá jẹ)
Ẹ̀yin èrò ká relé Aláyìndé o
Lọ́dọ̀ Ayédáadé (ká relé aláyìndé o)
(Ká lọ f’ewúrẹ́ ji’yán ká fi champagne gbọnra nù o)
Ah! Àyìndé mi Musiliu (Egúngún Ayédáadé)
Èèyàn Lékan ọmọ Bismillahi (egúngún Ayédáadé)
Èèyàn Lékan ọmọ Bismillahi (egúngún Ayédáadé)
Iṣan ọrùn big London
Èèyàn ti Kamoli pappy (egúngún ayédáadé)
Èèyàn Hessy Suliya bàbá ìbejì
Ko ma bá mi tọ́jú Zuzu (egúngún ayédáadé)
Èèyàn olówó ni Sule (egúngún ayédáadé)
Èèyàn t’olówó ni Sule (Sule maito)
Èèyàn t’owó (Owónikó Owónikókó)
Èèyàn ti mèwúrù Jimoh (Owónikókó)
Èèyàn Káká Ìjẹ̀sà Káká mo kí ẹ kí ẹ (Owónikókó)
Èèyàn ti Jimoh wewuru (Owónikókó)
Èèyàn dúdú olúọmọ
Èèyàn Màláíkà Èjìgbò
Èèyàn Bọ́sẹ̀dé Ody mama
Èèyàn Chinasa
Máa bá mi tọ́jú Bukky (egúngún Ayédáadé)
Títí Àbẹ̀bí olúọmọ, Bọ́lá, Bukky, Ọ̀túnba Dubai
Ody mama tí à ń wí rèé o (ko sọ̀kọ́ ijó o)
Èèyàn ni Ody èèyàn ni
Ody mamà tí à ń wí rèé o (ko sọ̀kọ́ ijó o)
Èèyàn Déọlá Dior Ody mama tí à ń wí rèé o(ko sọ̀kọ́ ijó o)